Smiley face

IGBIN KI I JEYO

Alagbara ni Oluwa wa, ona to ba wu Edua oke lo le gba se afihan Ogo-Ola re.

Nje eyin mo wi pe igbin le pada wu oju miiran bi igba ti omode n wu ehin tuntun jade ni igbakigba ti o ba ti padanu oju to ni tele?

E yii le nira lati gba gege bi otito oro, sugbon ododo oro ni.

Eni to wu Oba oke lo n da lola, ona ra si ni ise owo Re.

Olayemi Oniroyin, titi lai ni i maa royin ise Oluwa oba.

E ku Ikale!
28EEEAE2
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment