Smiley face

Akala Ti Lo Je Amala Nile Ladoja

Oselu Ibadan, opo awon eniyan gba wi pe oselu alamala ni. Se ka gba wi pe amala yii kan naa lo da Akala ati Ladoja po bayii.

Nje eti gbo?

Won ni won kefin Akala ni ile Ladoja ni Ibadan ti won jo n se ipade po.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment