Smiley face

OWO DANGOTE YARO

Atejade miiran ti jade eyi to n se afihan ipo Aliko Dangote ninu awon to lowo ju lagbaye. Ipo karundinlogbon ni omo wukuwuku wa bayii ninu awon olowo aye eyi ti otun se afi han re gege bi omo adulawo akoko eyi ti o ni dukia to to ogun bilionu dola owo ile Amerika.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment