Smiley face

Eniyan Mejila Poora Ni Mexico

Awon olopa ti gbe awon eniyan meta kan ti mole ni ilu Mexico latari awon eniyan mejila kan ti won sadeede poora ni ile igbafe ijo kan ni ilu naa.

Pupo ninu awon eniyan ti won poora yi ti won je odo ni won wa lati agbegbe kan ti n je Tepito.

Awon isele buruku ki a maa ji awon eniyan gbe yii ti gbile gan-an ni ilu Mexico to je wi pe laaarin odun bi mefa seyin awon eniyan ti won to egberun merindinlogbon ni won ti poora lojiji.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment