Owo awon olopa ile India ti te awon okunrin meta kan ti won fura si wi pe won lowo ninu iwa ifi-ipa-ba-ni-lo-po kan to sele si omobirin ile Ameika kan.
Gege bi a se gbo isele naa, omo obirin yii n bo lati ile ijosin Hindu ni arewa ile India ki o to bo sowo awon eniyan onise ibi wonyii.
Bayii, oga olopa Vinod Kumar Dhawan so wi pe iwadii si n tesiwaju lati mu gbogbo awon amookun seka naa.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment