Olori ile South Africa fun igba kan ri, eni ti gbogbo agbaye tun mo si Baba Ile alawo dudu, Nelson Mandela tun ti pada si ile iwosan fun igba keta ninu odun yii. Mandela eni ti yoo pe omo odun Marundinlogorun(95) losu to n bo ni won ti da dubule bayii ni ile iwosan Pretoria fun itoju ona ofun to n yo o lenu lati igba yi wa.
Adura wa ni wi pe ki Olorun oga ogo ju lo ba fun ni alaafia. Amin
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment