Sebi won ni ori ade ki i sunta ni? Oro ko ri bee pelu Oba Egbin ti Ikorodu, Oba Adeoriyomi Obateru. Oba Obateru ati awon mijidinlaadota kan ti wa ni gbaga awon olopa bayii ni kirikiri latari esun apaniyan ti won fi kan won.
A gbo wi pe oba yii lowo ninu ona aito ti won gba pa olopa kan ti oruko re n je inpeto Ikpi Ikipi. Bi o tile je wi pe awon wonyi ti fara han ni ile ejo, sibesibe onidajo Demi-Ajayi tun ni ki won da won pada si kirikiri ki won lo maa ta ludo na ki won to mo iru idajo to ye fun won.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment