Fonoloji: Aranmo (Assimilation) ninu ede Yoruba |
Ninu folọnoji ede Yoruba, ohun ti a n pe ni Aranmọ (Assimilation)
maa n waye nigba ti awon iro ohun meji ba di toko-taye. Eyi tunmu is ìlèpọ̀
laaarin awon ohun meji.
Gege bi Kola Owolabi 1989 se saleye fun wa, iro kan le
mu lara abuda iro keji nigba ti won ba di okan tabi beekọ.
Gege bi alaye Francis Oyebade, 1998, Oun se ninu alaye
ti ẹ wi pe Aranmo yii le jẹ Anticipatory, eleyii ti yoo mu iro ohun isaaju
lati yọ mọ iro eleekeji. Bakan naa ni iro tẹyin le yọ mọ ti isaaju eleyii
to pe ni Perseverative Assimilation.
Ju gbogbo rẹ lọ, o dabi eni wi pe oko kan naa ni Francis
Oyebade ati Kola Owolabi jo n ro.
Ninu Apeere Kola Owolabi
Ilé ìwé =
iléèwé
Ọ̀wọ́ ọ̀wọ́
= ọ̀wọ̀ọ̀wọ̀
Apeere Francis Oyebade
Ara oko = Araoko
Ọmọ Ẹran = Ọmọeran
Gege bi a ti se alaye siwaju, èrò Kola Owolabi ati
Francis kò yato si ara won. Kola Owolabi gba wi pe, ọ̀nà mẹta ni a le pin
awon aranmo si ni ile Yoruba.
Awon ona meta naa ni
Aranmọwaju ati Aranmẹyin
Aranmọ alaiforo (alai-fo-iro) ati aranmo aforo (a fo-
iro)
Aranmọ kíkún ati aranmo ẹlẹ́bẹ
0 comments:
Post a Comment