Aroba Baba Itan: Aworan Atiku Abubakar Nigba Ti N Se Ise Asobode
Eyi ni aworan igbakeji Aare fun igba kan ri, Alh Atiku Abubakar nigba to wa lenu ise asobode ile Naijeria. A gbo wi pe odun 1989 lo fi ise naa sile lati gbe igba oselu ati okoowo sise.
0 comments:
Post a Comment