Femi Kuti Ko Awon Omo Re Bo Soju Agbo
Sebi awon Yooba lo ni oosa taa ba n sin ta n le omo kekere kuro nidi re, won ni iru oosa bee ki i pe parun. Lojo Aiku to koja yii lari Femi Kuti to ko awon omo re wa soju agbo ere orin Afro. Iwadii fi ye wa wi pe igba akoko ko ni yii ti Femi yoo ma ko awon omo wonyii jade lo si ode ere orin kiko. Oni lati je wi pe baba won fe ki won mo nipa orisii ise to so ohun di aniyikaye ni.
0 comments:
Post a Comment