Smiley face

Ijo Irapada Setan Ati Ko Gbongan Eleyii To Gun To Kilomita Meta

Ijo Irapada eleyii ti a mo si Redeem Christian Church of God ti setan bayii lati ko ile ijosin tuntun eleyii ti yoo gun to kilomita meta. Baba Adeboye lo so eleyii nibi ipago odun yii ti won setan lose to koja. Gbongan nla ti won n lo lowo, eleyii to gba to milionu kan eniyan naa lo ti n fun gaga bayii.


Ajanaku ki i se eru omode. O ni lati je wi pe Olorun gan-an ni i ko ijo re looto. Nitori ti eniyan yoo ba rin irin kilomita meta nnkan bi ogoji iseju ni yoo lo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment