Okan lara eto Oselenkejo ti Akolawole Olootu lori redio nibi ti Wasiu
Alabi(Oga Nla1) ti gbe ba ni alejo. Kola Olootu je Gomina egbe sorosoro
(FIBAN) eka ti Ipinle Oyo. Eto Oselenkejo ti Kola Olootu ti o maa n se
lori radio si je okan lara awon eto to gbajugbaja ni Iwo Oorun ile
Naijeria.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment