Smiley face

Fidio Orin P-Square Wo Inu Iroyin Agbaye

Fidio orin tuntun 'Personally' ti awon omo ibeji olorin takasu ile Naijeria ti amo si P-Square se ni won ni onka oju-iran re lori Youtube ti le ni Milionu meji.

Se kii se wi pe aworo to daju ni awon omo olorin yii nlo? (Erkk) Abi ki lo le fa opolopo awon eniyan ti won tu ketiketi lo wo fidio won lojoojumo ti okiki won si tun bo n kan si.

Olayemi Oniroyin, emi gba wi pe ti Edua oke ba ni akoko eni ti to, bi ogun ni i jo loju omo araye. Ogun si ko, Ori eni ni i pe ko ye ni.

http://www.youtube.com/watch?
v=ttdU19Kwce8&sa=X&ei=FPoIUrjCB4XUtAbUuo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment