Smiley face

Al Qaeda Tun Fe Be Amerika Wo

Awon omo ogun alakatakiti esin Islam ti a mo si Al Qaeda tun setan lati se abewo si ilu Amerika bayii. Atejade tuntun yii lo waye lati enu Jihadiya Salafiya ti o je okan lara awon asaaju egbe naa nibi ti o ti n leri wi pe dandan ni esin Islam gbodo di itewogba kaakiri aye.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment