Smiley face

Won Ri Ejo Nla Ni Ilu Florida

Okunrin kan ti n gbe ni goosu ilu Florida lagbo wi pe o ri ejo sebe nla kan labe atibaba re ni bi to ti n pale ile mo. Ejo yii lagbo wi pe ogun to bata ese metala, eleyii ti won fura si wi pe ni o ti wa labe atibaba naa fun igba die seyin.

Won ba iho(awo) ejo naa eleyii to ti bo sile tele ati ajeku olongbo kan ti won ti n wa ni inu ile naa labe atibaba ti won ti ri ejo yii.

Ojo Aiku to koja yii ni okunrin onile naa kan gbero ati se ise kole-kodoti gbogbo ile re. Ibe lo ti kefin ejo naa ti won si sare kesi awon alaabo ilu fun iranlowo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment