Smiley face

I GO DYE Setan Ati Ra Moto Ogbon Milionu Naira

Omokunrin Alawada ti a mo si 'I Go Dye' la gbo wi pe o ti fi owo toto bi Ogbon Milionu(30M) ranse silu okeere lati ra orisii oko ti a mo si Rolls Royce phantom.

E maa gbagbe wi pe omokunri yii ni oko Cadillac Escalade eleyii to fi n jaye werewere. Bakan naa la tun gbo wi pe o tun un ko ile nla kan lowo bayii ni ilu Benin.

Gbogbo wa pata la ba onire yo!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment