Ni ana ode yii ni gbogbo aye se iranti akoni elere boolu alafesegba omo Naijeria, Samuel Okwaraji ti o di oloogbe ni Ojo Kejila Osu Kejo Odun 1989 ni papa isere ti Ijoba Apapo to wa ni Surulere nibi ifesewonse to waye laaarin ile Naijeria ati Angola.
Iseju die naa lo ku ki ere boolu naa pari, ni Samuel ba subu lule. Samuel Okwaraji subu, kosi le dide mo.
O ti pe odun merinlelogun bayii ti Sam ti lo, gbogbo wa la n se idaro akoni.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment