Smiley face

Oro Lori ASUU

Ipade si n tesiwaju laaarin Ijoba apapo ati Egbe ASUU lowolowo bayii. Bi o tile je wi pe Ijoba Apapo n ro won lati pada si enu ise won, nigba ti eto yoko n tesiwaju. Sibesibe, iko mejeeji ko ti fenu ko sibi kankan. Enu lasan ni ijoba apapo fi n be won, eto ASUU ko ti te won lowo.

Alaye si n tesiwaju
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment