Smiley face

Funke Akindele N Se Sinima Jennifer Tuntun Lowo

Funke Akindele ti fi da awon ololufe re loju wi pe oun ti n se sinima tuntun Jennifer mii lowo eleyii ti ko ni pe jade. Sinima yii lagbo wi pe won o ya awon aworan re ni ilu Amerika.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment