Smiley face

GTBank Ti Gbe Idunadura Won De Ori Facebook

Nibayii, ile ifowopamo kan ti a mo si GTBank ti gbe idunadura won wo ori ete Facebook bayii.

Won ni e le si apo ifowopawo tuntun lori Facebook ti won o si fun yin ni nomba apo ifowopomo yin laisilokabo rara. Lara ohun ti a gbo wi pe won se ni wi pe e le mo iye owo to ku ninu apo ifowopamo yin. Bakan naa le tun le ra akoko ipe si ori ago lati inu owo te e fi pamo sodo won.

Fun alaye lekunrere (bi won ko tile fise ran mi), e kan si won lori: www.facebook.com/gtbank

Lobatan
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment