Smiley face

'Baba, E Sora Yin O" GEJ Juko Oro Si Bisi Akande

Aare Goodluck ti fesi ranse lojo Abameta to koja yii si olori egbe tuntun APC, Oloye Bisi Akande wi pe ki baba ya ara re ni opolo gidigidi bi o ba fe te.

Eleyii waye latari oro kan ti won ni Oloye Bisi Akande so nibi iponlogo egbe APC. Nibi ti o ti so wi pe Aare n dari ilu bi mojesin ti ko mo ju ko jeun lo, ko si yi taya.

O dabi eni wi pe oro yii dun oko Patience gan-an. Abi ki lo le fa ibinu, to si n leri wi pe ti iru oro katikati bee ba tun waye, ofin yoo gbe odindi Oloye fun esun ibanilorukoje.

E jowo, e je ki n dake naa. Ko ma di wi pe won fi esun 'ibani-niroyinje' kan mi.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment