Aare Goodluck Jonathan Ti Lo Si Jerusalemu Olayemi Oniroyin 10/23/2013 12:25:00 pm Oro Oselu Edit Laaro oni yii ni Aare Goodluck ati awon gomina bi mokandilogun gbera lo si ilu Isireli lati lo si Jerusalemu mimo. Awon gomina nikan ko ni won tele Aare, awon minisita naa wonu baalu to fo ni aaro oni yii. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Àkúrẹ́ mi tìtì: Òkìkí Omoyele Sowor...Omoyele Sowore ṣe àbẹ̀wò sì Deji ti..."Ìyẹ́ ni wọn o má wo lẹ́yìn ẹy... Aare Goodluck Jonathan Ti Lo Si Jerusalemu Reviewed by Olayemi Oniroyin on 10/23/2013 12:25:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment