Sebi awon Yoruba lo ni eni ti won ba ta lofa ni i japoro.
Leyin ti egbe agbagboolu Super Eagle din dunundun iya fun alatako won,Walya Antelope ti ilu Ethiopia, ni awon omo Ethiopia ba da gbogbo oro ru bi ti onibode Lalupon.
Ogulutu nlanla ni won so lu moto bogini nla to n ko awon omo Super Eagle pada sile itura ti won de si leyin ifesewonse naa.
Okan ninu awon okuta naa si ba Nosa Igiebor eleyii to fa atelewo re ya peregede bi owo aso.
Aimoye awon omo Naijeria ti won sise aje ni ilu naa lagbo wi pe won tun na sare ti gbogbo won si n sare kabakaba kiri igboro,
Nibayii,won ti fi isele naa to ajo FIFA leti, a si gbagbo wi pe awon alase boolu agbaye yoo se ohun to ye nipa oro naa.

0 comments:
Post a Comment