Won Ti Da Charles Taylor Pada Si ilu UK Lati Lo Pari Ewon Aadota(50) Odun Ti Won Fi Ta Lore
Aare ile Liberia to je laaarin odun 1997 si 2003, Ogbeni Charles Ghankay Taylor ni won ti gbe lo si United Kingdom lati Holand laaro oni lati lo pari ewon aadota odun(50yrs) ti won fi ta lore latari ebi esun iwa odaju si iran omoniyan ati awon iwa buruku mii ti ajo UN ka si lese ni ile ejo.
0 comments:
Post a Comment