Odun Kristeni ati Musulumi ti dohun ajose, sebi eyokan naa ni gbogbo wa.
Bi o tile je wi pe orun ti mo n sun lonii ko je ki n ranti mo wi pe oni lodun ileya. Sugbon Ayinla Omowura to gba adugbo mi kankan ko je n gbagbe wi pe eran dindin pelu iresi joloofu yoo ti dele.
Olayemi Oniroyin, mo fe fi asiko yii ki awon ololufe wa ti won je Musulumi ododo ku odun ileya. Emi wa yoo se opolopo odun laye ninu owo ati alaafia.
E ma je n tan yin, otito ni wi pe bi onirefin ko ba fingba mo, eleyii to ti fin sile ko le parun lailai.
Bi Ayinla Omowura se n fi oyinbo korin, bee ni awon elegbe re n so itunmo re. Anigilaje ni lu ilu alujo lowo. O ga ju!
E ku dun.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment