Smiley face

Oosa Ilu Oyo N Se Ojo Ibi Lowo

Olayiwola n binu lowo, won sare lo re e bo Osun. Awon eni oro ko ye ko mo wi pe oosa bibo ko tanran. Tani in pe Oba lalase ekeji orisa?

Ti won ba n pe oba lalase ekeji orisa, bi oba Lamidi ko, oba ju oba lo, Oosa gan-angan ni Lamidi.

Omo Adeyemi mo pe o loruko lonii, sebi oruko ni won pe ojulowo oba gidi.

Mo ki o, o ku ayeye ojo ibi re to ko layo. Igba odun, odun kan ni fun o. Ase.

Ojo keedogun osu kewa odun 1938 ni akosile fi ye wa wi pe won bi Lamidi Olayiwola Adeyemi III. Oba Gbadegesin Ladigbolu II lo je oba ki Lamidi to gori ite ni odun 1970.

Lamidi Olayiwola Adeyemi III pe eni odun marunlelaadorin (75)lonii, gbogbo ilu Oyo lo mi titi.

Kongiratulasan!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment