Baalu kan lo ja pada wa sile leyin iseju die to gbera kuro nile bo si oju afefe laaro oni yii ni ilu Belgium.
Baalu yii lagbo wi pe o gbe awon elere idaraya alefo-soju-orun ti a mo si 'parachute'.
A gbo wi pe won fe lo se ayeye fun okan lara won ti n se ojo ibi pelu orisiirisii idaraya ilefo soju orun sugbon kadara ko gba fun won.
Gbogbo eniyan ti n be ninu baalu pata lo ku ti enikeni ko si le so pato ohun to fa isele buruku yii di akoko yii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment