Smiley face

Ijamba Oko Ni Ipinle Ondo

Ijamba oko kan waye lopin ose to koja yii ni Igbara-Oke to wa ni ijoba ibile Ifedore ni Ipinle Ondo.

Ijamba oko yii lagbo wi pe o mu emi eniyan merin kuro laye koja si ajule orun.

Edumare ma je ka rin loju ebi n pona. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment