Peter Okoye ti da ojo igbeyawo re sona bayii. Ayeye igbeyawo yii ni yoo bere pelu igbeyawo tiwantiwa, eleyii ti yoo waye lojo ketadinlogun osu kokanla (November 17th) ni Arc Events Centre to wa ni Lekki.
Gbenga Adeyinka ati Helen Paul la gbo wi pe won yoo dari yeye igbeyawo alarinrin naa.
Gbenga Adeyinka ati Helen Paul la gbo wi pe won yoo dari yeye igbeyawo alarinrin naa.
0 comments:
Post a Comment