Smiley face

Case Study: De Good Ati De Ultimate

De Good Ati De Ultimate
 

O ti pe ti oro Naijeria ti je oba Fuji logun, bi o se n ko lorin ni ko ye e so tinu re fun awon oniroyin.

Lara ohun ijoloju ti Baba Yomade se ni nigba to korin ki Obasanjo, 'E fun baba laye ki baba o san jo'. Nigba ti baba ko ti ko sanjo, Ayinde tun korin tuntun lati tako Baba Iyabo.

Lati kekere ti won ti bi Adewale Dada lo ti je wi pe aso ala funfun ni fi n soge. Bi ko ba wo funfun yoo wo giriini alawo ewe.

Asia Naijeria ko si lawo meji koja funfun ati awo ewe naa lo.

Aimoye ise opolo ni Alao ti se lati pe akiyesi awon ijoba si igbe aye awon mekunnu eleyii ti ko dara rara. Eru ki i ba De Good, a ni ise Oluwa ni mo n je.

Wasiu Ayinde ati Wale Dada ti pe ninu ka ja fun ara ilu nipa ilo ise opolo bi orin, agbekale awada ati afihan ogbon atinuda.

Kini o mu won ni ero kan naa? Abi tori wi pe won jo wa lati Ipinle Ogun kan naa ni?

Bi eyikeyi ninu won ba gbe apoti idibo, nje eyin le dibo fun won bi?

Olayemi Oniroyin, emi duro na lati reti awon esi yin.

E ku asiko yii!


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

14 comments:

  1. Ti K1 ba je President ki Wale je Vice President.. O kan je wi pe ahun ni Wasiu ni. Awon Ijebu lahun. Owo lo de maa n boju ore je lol

    ReplyDelete
  2. Case Study gbaaa ni awon mejeeji. Awon omo Ipinle kan naa, Ti mo ba ti fe ko Project mi, ma consider topic yen,

    ReplyDelete
  3. Olayemi Oniroyin, E ku akiyesi. Sugbon awon oloselu wa ko le gba ki iru awon eleyii de ori ipo. sebi e rant Fela, Gani pastor Bakere ati won to ko. e ni to maa fi iya je ara ilu nikan nii won fun laye lati di ipo alase mu

    ReplyDelete
  4. E mi maa dibo fun won ooo. Oba Fuji de Ultimate

    ReplyDelete
  5. Walahi, mmaa dibbo fun won.

    ReplyDelete
  6. Se ki se wi pe won fe gbe apoti idibo lotito. emi a gba won ni imoran ki won koko gbe appoti idi ni gomina naa. ki won de maa lo egbe Pdp oooo. Olorun a fun won se.

    ReplyDelete
  7. konbinasa to baadi. ka maa paro awon mejeeji ti ggbiyan jju gan gidi. nipa oro naijeria gege bi olorun se fun won lagbara mo. mo si gba ladura wi pe olorun yoo tun bo maa gba fun won

    ReplyDelete
  8. E mi maa dibo fun won oooo. D good ti ko ni baadi lailai

    ReplyDelete
  9. olooto ilu ni osika ilu

    ReplyDelete
  10. Awon mejeeji kan se ohun ti Olorun fi ran won ni. Emi o ro wi pe boya to ri ki won le gbe apoti idibo ni won se n se gbogbo akitiya won. Ki Olorun bukun Naijeria. Ti a ba ni irun won bi Ogorun, eru yoo maa ba awon ijoba wa lati maa wu iwa ika.

    ReplyDelete
  11. Huuuuuuu adara toba legba kikan ninu awon mejeji laye amo awon oloselu wa,awon obaye je onigba afi tolorun oba ba koko mu iru awon obaye je kuro loku ki olorun gba isakoso

    ReplyDelete
  12. D̶̲̥̅̊i̶̲̥̅̊s̶̲̥̅̊ world α̲̅я̩̥̊ε̲̣̣̣̥ so full ☺f̶̲̥̅ lies so as ƒσя ♍ƺ ℓ̊ trust N̶̲̥̅̊☺ one, abi Tani won ma fun ni OKO ti ko ni ro OKO si ODO ara re, ℓ̊ N̶̲̥̅̊☺ go vote bcos since ℓ̊ was born ℓ̊ never vote ƒσя M̶̲̥̅γ̲̣̣̥ life bcos U̶̲̥̅̊r vote α̲̅я̩̥̊ε̲̣̣̣̥ not count Ȋ̝̊̅§ just a waste ☺f̶̲̥̅. time

    ReplyDelete
  13. Otito oro lo so. Kosi eni ti won maa gbe gori esin ti ko ni so ipako seyin. Sugbon emi gbagbo wi pe oselu Naigeria ni lati fi aye sile fun awon eniyan tuntun ti won ni ero rere lokan fun Nigeria. Orisi awon eniyan kan naa ni won ti n dari wa ti pe. Family kan naa lo lead Nigeria lati 1960 a ni lati gbiyanju awon eniyan tuntun. Nigeria si maa dun, amin

    ReplyDelete