Awon Yoruba bo, won ni ile oba to jo, ewa lo bu si. Davido ti beere si ni i tun fidio orin Skelewu re ya bayii ni ilu London. Gege bi e se mo, fidio orin yii ni Davido ti ya tele eleyii to so wi pe awon olote kan gbe sita lona aito ati wi pe fidio orin naa ko wu oun mo. Eyi lo mu Davido pada si ilu London lati lo tun orin naa ya lakotun.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment