Smiley face

Iji Nla Ja Ni Ilu Japan

Ni erekusu to wa ni ilu Tokyo, Izu Oshima ni iji nla kan ti sadeede n fe kikankikan pelu owo agbara eleyii to si ti la emi lo bayii. Aimoye ile lo ti wo, aimoye dukia lo ti parun, awon eniyan bi metadilogun lo si ti jade laye latari isele to sele lojoru to koja yii.
 
 
Lowolowo bayii, awon eniyan bi aadota ni enikeni ko mo ibi ti won wole si mo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment