Master Nau |
Olayemi Oniroyin, ilu Nepal ni mo ti gbe ri baba agbalagba kan ti gbogbo eniyan mo si Master Nau, eni odun metalelaadorin (73). Baba yii ni iwadii fi ye wa wi pe ohun ni eniyan to je okunrin to kuru ju lo ni gbogbo agbaye pelu bi giga re ko se ju iwon ese bata merindinlogun lo (16ft).
Nibayii, awon ajo Guinness World Record ti fi o onte lu Master Nau.
Won si ti setan lati gba irawo eni-okunrin-to-kuru-ju-lo ni gbogbo agbaye lowo omo ile Taiwan ti oun ga ni nnkan bi iwon ese bata metadilogbon (27ft) ti o n di ipo naa mu lowolowo.
Olayemi ti mo ba ti soro to ba ti tase ara awon, e maa tun mi se. Sebi enikan ki i gbon tan. Oniroyin agbaye, ti mo ba ba tigba kan bo okan ninu, n se ni ke e tu mi si gbangban.
Sebi eni koko kola, ika ni won se fun un. igba to ya ni ilakiko doge. Master Nau ti dere apesin ni ilu Nepal. Sebi o wu Eledumare lo so egan dogo laye eni ti gbogbo eniyan wo gege bi idoti.
E ku ikale!
0 comments:
Post a Comment