Sebi Oba Oyekan lo fi Oba Fuji Je Oluomo of Lagos. Oba Akiolu lo fi
Folashade Tinubu je Iyaloja of Lagos. Awon agbaagba ba pe birikoto, won
ni eni mo adun oba lo le korin oba gidi.
Idi pataki re e ti won fi pe K1 De Ultimate lati wa
sere nibi iwuye omo Bola Tinubu, Folasade Tinubu Ojo ti Oba Eko fi je
oye Iyaloja.
Olayemi Oniroyin, ode orin oba Fuji dun gan-annnnNnnnnnnnNnnnn
se e de ibe ni? ba wo le se mo
ReplyDeleteAwa nibe now. Ti a ko ba si nibe ba wo la se fe mu iroyin wale. Te e ba fe mo boya mo wa nibe abi beeko . E pade mi lori mi. #sempe level
ReplyDelete