Smiley face

Won Ti Kede Awon Agbaboolu Pindan-pindan Ori Odan Ti Won Seese Ki won De Ade Ogo Odun Yii Gege Bi Agbaboolu To Dara Ju Lo Ni Gbogbo Agbaye


Won ti kede awon agbaboolu sankosanko metalelogun(23) kaakiri agbaye to je wi pi inu won ni won yoo ti yan agbaboolu agbaye kan soso to dara ju fun odun.

Awon agba boolu naa ni yii:

(1) Gareth Bale (Real Madrid/Wales)
(2) Philipp Lahm (Bayern Munich/Germany)
(3) Thomas Muller (Bayern Munich/Germany)
(4) Manuel Neuer (B ayern Munich/Germany)
(5) Bastian Schweinsteiger (Bayern Munich/
Germany)
(6) Mesut Ozil (Arsenal/Germany)
(7) Robin van Persie (Man United/Netherlands)
(8) Arjen Robben (Bayern Munich/Netherlands)
(9) Edinson Cavani (PSG/Uruguay)
(10) Luis Suarez (Liverpool/Uruguay)

(11) Andres Iniesta (Barcelona/Spain)
(12) Xavi (Barcelona/Spain)
(13) Neymar (Barcelona/Brazil)
(14) Thiago Silva (PSG/Brazil)
(15) Radamel Falcao (Monaco/Colombia)
(16) Andrea Pirlo (Juventus/Italy)
(17) Frank Ribery (Bayern Munich/France)
(18) Cristiano Ronaldo (Real Madrid/Portugal)
(19) Eden Hazard (Chelsea/Belgium)
(20) Zlatan Ibrahimovic (PSG/ Sweden)
(21) Robert Lewandowski (Dortmund/Poland)
(22) Lionel Messi (Barcelona/ Argentina)
(23) Yaya Toure (Manchester City/Ivory Coast)


Abala ti awon olukoni elere boolu alafesegba.
Inu awon wonyii ni won yoo ti yan olukoni to dara ju lo ni gbogbo agbaye fun odun:

(1) Carlo Ancelotti (Real Madrid)
(2) Rafael Benitez (Napoli)
(3) Antonio Conte (Juventus)
(4) Vicente Del Bosque (Spain)
(5) Sir Alex Ferguson (ex-Manchester United)
(6) Jupp Heynckes (ex-Bayern Munich)
(7) Jurgen Klopp (Borussia Dortmund)
(8) Jose Mourinho (Chelsea)
(9) Luiz Felipe Scolari (Brazil)
(10) Arsene Wenger (Arsenal)


Tani eyin lero wi pe yoo je agbaboolu agbaye to dara ju lo fun odun? Tabi olukoni wo leyin ro wi pe o pegede ju lo?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment