Ilu Eko mi titi lana nigba ti Oba Rilwan Akiolu (Olowo Eko) fi akobi omo obirin Ahmed Bola Tinubu, Folashade Tinubu Ojo je oye Iyaloja gbogbo Ipinle Eko patapata ni aafin re.
Oye Iyaloja yii lo je wi pe iya Tinubu lo ti n je saaju ko to pa ipo da.
Olayemi Oniroyin, mo ki oloye tuntun. Asiko Sade yoo tu wa lara. Ki gbogbo oloja maa ta ata jere, ki awon onisowo maa rowo saye, ki gbogbo onise owo maa rise. Ki a wa oniroyin naa ma ri ohun royin nigba gbogbo (erkk). Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment