Olayemi Oniroyin, sebi eti oba nile eti oba loko eniyan ni i je be.
Okan ninu awon eniyan to wa nibi ipade ijoba apapo ati egbe ASUU ti fi ye wa wi pe oseese ki ASUU da iyanse lodi won duro laipe.
Eleyii lo jeyo pelu bi ijoba ati egbe ASUU se fi imo sokan leyin ifikunlukun won to waye.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
Olorun a je ko ri bee wo. Ile ti su wa oo
ReplyDelete