Egbe ASUU ti sun ojo ipade won siwaju eleyii to ye ko waye lana ode yii nibi ti won ti fe jiroro nipa fifagile iyanselodi ti n lo lowo.
Aba yii lo wa lati odo olori egbe ASUU, Nasir Fagge latari ijamba oko to seku pa olori egbe naa nigba kan ri, Festus Iyayi nigba to n lo si ipade egbe ASUU.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment