Bi o tile je wi pe awon dokita ni ko maa lo sile ninu osu kesan-an leyin osu meta to ti wa ni osibitu latari aisan ona ofun ti n yo Mandela eni odun marundinlogorun(95) lenu, owo itoju awon dokita ko kuro lara re ni ile re ti won gbe lo lati igba naa.
Gege bi aya re nigba kan, Winnie Madikizela-Mandela se so fun awon oniroyin:
"Mandela ko le fo ohun jade mo, oju ati owo ni fi n soro bayii. Sugbon awon dokita se ileri wi pe oseese ki ilera re bosipo laipe eleyii ti yoo si le fohun jade pada"
Edumare ba wa fun ni alaafia. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment