Otunba Kola Olootu |
Olootu so fun mi wi pe orisii olowo meji lo wa laye. Olowo ti n nawo ati eyi ti ki i na.
"Kosi aponle ati iyi fun olowo to da ohun gbogbo toni je lai fun enikankan je. Igbe aye olowo ko ni itunmo bikose eyi to fi owo ran igbe aye iran omoniyan lowo."
Kola Olootu se ojo-ibi lonii, gbogbo aye ni won dide lati se aponle eniyan pataki. Aye ye Gomina gbogbo egbe sorosoro Ipinle Oyo lonii, ki i se nipa owo tabi ogbon Olootu bikose bo se lo ohun ti Edua Oke fun un lati mu igbe aye awon eniyan ladun ju ti tele lo.
Baba mi, adura mi ko po. Ohun ti mo beere lowo Olorun oba fun yin ni alaafia ati emi gigun, mo beere owo to ju owo lo, mi o si gbagbe ayo ati idunnu. Gbogbo e pata ko maa je ti yin. Amin.
Bo ti wu ko ni daa to, ola yoo daa ju bee lo.
Happy Birthday!
To ba je wi pe won soro joba ni Kola Olootu ti to jOba Alade. Happy Birthday
ReplyDeleteHappy Birthday omoadabanija. LLNP
ReplyDeleteKola Olootu omoolojo ibi, asodun modun ni awo asodun modun. Asoro moro ni awo asoromoro. Igba odun odun kan ni. Amin Happy Birthday
ReplyDeleteHappy Birthday to u. Long life and plenty money. #onselekenjo gan ni ooooooooooooooooooooooooo
ReplyDeleteHBD
ReplyDeleteI appraciate all the comments. Thanks. #HBD
ReplyDeleteOmo eni ija o ba ti n pe ara re ni complete man. We love u. Long life and plenty money. HBD
ReplyDeletePlease, kindly bring our cake on your radio programme on wed oooo. HBD. Sure father
ReplyDeleteHappy Birthday
ReplyDelete