Smiley face

Ofofo: Iyawo Gomina Ti Ko Jade Nile O

Ani iyawo gomina Ipinle Enugu, Arabinrin Clara Chime ti fi ibinu kojade ni ile oko re laaro ana. Won ni ile iya re lo lo dalemosu si bayii.

O ti to bi ojo meta kan ti aarin ohun ati oko re ko gun rege. Awon ebi iyawo si ti wa ba won pari ija naa sugbon o dabi eni wi pe ija naa ko pari tan.

Nibayii, iyawo ti ko jade lo joko si ile iya re.

E dakun, e maa so wi pe enu mi leti gbo ooo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment