Smiley face

Rere Run: Boko Haram Pa Oko Iyawo Tuntun Pelu Ebi

Awon omo Boko Haram pitu owo won lana ode yii nigba ti won fi emi awon eniyan ti won ko di ni ogbon sofo bi omi isanwo.

Awon eniyan yii ni won n bo lati ibi ayeye Igbeyawo ti won se ni Michika to sun mo ipinle Adamawa lo si olu ipinle Borno ti n se Maiduguri.

Ni agbedemeji oju ona Bama-Banki ni awon omo Boko Haram ti da won lona ti won si pa awon eniyan ti won n ti ode ariya bo ni ipakupa.

Oko iyawo ti o ye ko sun ti iyawo lale naa sun sinu agbara eje nla ti n san loju titi bi odo ogunpa.

Rere run o!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment