O ti pe ti Saheed Balogun ti n kilo fun aya re nigba kan ri, Fathia Balogun wi pe ko ye e je oruko oun mo. Sugbon Fathia ko ye e je Balogun nigba ti o je wi pe oruko ti opolopo mo si nu un lagbo amuludun.
Fathia gan-an si ti fesi rense lojo to ti pe wi pe Balogun ti oun je kosi eni to le ja leyin oruko oun ati wi pe won ti toje bo oloosa lowo , ko si baba nla eni to le bo.
Ibi igbeyin oro maa jasi ni ko ti ye enikeni. Ohun adajo fe da lejo kosi eni to le mo. Titi gbogbo oro yoo fi lari mo ibi kan, Olayemi Oniroyin gan-an ni oniroyin yin.
E ku ikale

Elèyí tun ni agbara o
ReplyDeleteAbi oo. Ki Olorun saanu fun wa. Ti oro ife ba ti koro, ko si ohun ti ko le waye
ReplyDeleteOro oko pelu aya aye emamadasi ko to to osun mefa apari ooooo
ReplyDelete