Leyin gbogbo darudapo to waye latari eto idibo gomina Ipinle Anambra, ajo INEC ti pada kede oludije fun ipo gomina labe egbe oselu All
Progressives Grand Alliance (APGA), Willie Obiano gege bi eni o jawe olubori.
A ki gomina tuntun ku ori ire pelu bo se wole ni awon ijoba ibile mokandinlogun(19) ninu ijoba ibile mokanlelogun(21).
Home / Uncategories / Leyin Gbogbo Rogbodiyan Ati Surutu To Waye Ni Ipinle Anambra, INEC Ti Gbade Fun Eni Ade Ye
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment