Smiley face

Satellite Setan To Fe Jabo Loju Orun


Awon onwoye imo sayensi ti kede wi pe oseese ki okan lara awon ero satellite ti awon oyinbo gbe si oju orun eleyii ti o n yi agbaye ka pin si meji yala ni ojo Aiku(Sunday) ti n bo yii tabi Ojo keji re to je Ojo Aje(Monday).

Won ni kete ti Satellite yii ba pin si meji, inu aye ni yoo jabo si. Sugbon won tun fi kun un wi pe ko daju wi pe yoo se ipalara fun enikeni nitori wi pe ilaji re yoo ti jona wuruwuru ko to dele, erunrun re lasan ni yoo kan fon si ori ile aye.

E ku oju lona!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment