Smiley face

Won Ni Ko Si Aye Fun Orobo Ninu Baalu

Kevin Chenais omo odun mejilelogun ti o je omo ile Faranse ni British Airways ti ko lati gbe bayii ni ilu Chicago. Won ni omo naa ti tobi ju, afaimo ko mo lo se akoba fun baalu loju orun.

Baalu yii kan naa lo gbe omo yii wa fun itoju ni ilu Amerika nibi ti Kevin ti n gba itoju.


"Se won le simgoomu moju tele ni? Abi won fe so wi pe awon ko mo ipo kevin ko to di wi pe a lo ra Ticket, abi awon naa ko lo gbe wa sibi ni?" Mama Kelvin

>>>
Nigba ti British Airways yari bayii, se a ko ni be Sosoliso tabi Dana ko lo ran Kevin lowo bayii?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment