Awon omo agbaboolu ile Naijeria, Golden Eaglets gbe ife eye boolu agbaye ti awon omo ti ojo ori won ko tayo metadinlogun lo ni irole oni ni Ilu Abi Dhabi.
Igba meta otooto ni won kona fun akegbe won lati ile Mexico ti won ko sile le ta puto.
Meta si odo layo pari si, Golden Eaglets ni won pade gbe ade fun.
Kongiratulasan!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment