Eyi ni awon egbe agbaboolu mewaa to tewon ju lo lagbaye nipa iye ti won to ti a ba gbewon si ori osuwon.
1. Real Madrid (£3300m)
2. Manchester United (£3165m)
3. FC Barcelona (£2600m)
4. Arsenal (£1326m)
5. Bayern Munich (£1309m)
6. AC Milan (£945m)
7. Chelsea (£901m)
8. Juventus (£694m)
9. Manchester City (£689m)
10. Liverpool (£651m)
Ti egbe agbaboolu ti yin ko ba si nibe, e maa fi sebinu. Oni lari, Edua lo mo bi ola o se ri. Ere la n fomo ayo se.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment