Smiley face

'Ayanmo Mi Ni' D'Prince Ra Oko Milionu Mejila Lai Gba Senji

Ariwo enu lasan ni wi pe ka maa kede wi pe orin ti dowo. Suti-ete lasan ni wi pe orin takasu Nigeria ti digi aloye.

Joojumo ni won n se ohun nla, joojumo ni i dowo gidi fun won.

D'Prince (aburo Don Jazzy) ti ja oko tuntun 2013 Mercedes Benz E Class Coupe bayii.

Gege bi a se gbo, won ni oko tuntun yii yoo to Milionu Mejila owo naira ile wa.

Olayemi Oniroyin, emi ba onire yoo lonii sebi ki ire le je temi naa ni.

Kongiratulasan!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment