Sebi awon Yoruba loni ti isu eni ba ta aa fowo bo je ni. Eyi ko ri bee pelu omo Fela Anikulapo ti oruko re n je Seun Kuti ati iyawo re, Yetunde Ademiluyi pelu bi won se gbe oyun akobi won han fun gbogbo aye ni goloto.
Emi o so wi pe o dara, bee si ni mi o ni o ku-die-kaaato. Bayi ni n se nnkan mi ko yipada.
Ki Edumare ba wa so igba di ayo funfun gbogbo abiamo aye. Ki gbogbo eni diwo-dise sinu bi were. Oosa Oke ba wa se omo alayo fun gbogbo eni n woju Oluwa oba.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment